Gospel powerhouse and worship leader, Tope Alabi has dropped a song titled, Ore Ofe Jesu.
Ore Ofe Jesu its off Tope Alabi recently released album tagged, Igbowoeda
RELATED: Tope Alabi – Hymnal Vol 1
However, this song is a Yoruba Nigerian Language an encouraging and faith-building song that emphasizes the sufficiency of God’s grace.
This is a soul lifting song with captivating lyrics, that should be added to your playlist this year.
Listen to Tope Alabi Ore Ofe Jesu and share your thoughts below.
https://www.youtube.com/watch?v=jIJD-XQgD-s
Tope Alabi – Ore Ofe Jesu MP3 DOWNLOAD
Tope Alabi – Ore Ofe Jesu Lyrics
Mo ri ire ayo ibukun
Mo ri ogo ayanmọ to Pin pere
Ola po jaburata, ọrọ agbon igbe
Gbogbo eyi ti mo ri eni lo ni won
Baba lo fi fun mi
Ore ofe Jesu
Ore ofe Jesu
Ore ofe Jesu ati anu lo to mi leyin
Ore ofe Jesu oo
Ore ofe Jesu oo
Ore ofe Jesu ati anu lo to mi leyin
Ọnà mi la igi aye dina ti wo womu womu
Dipo akete aisan sekere ọpẹ lo gbe le mi lọwọ
Bo ti wí tele ayo mi ku ko I tan oluwa ló tunmise
Isoji ọpẹ laye mi gba b’oluwa ti fe fún mi (b’oluwa se fẹ fun mi niyen)
Ore ofe Jesu
Ayo mi ku o po nle repete (ore ofe Jesu)
Ko le tan bẹẹni (ore ofe Jesu ati anu lo n to mi leyin)
Oluwa lo tunmise oo
Isoji ọpẹ laye mi gba
Mo ma gbe kiri ni (ore ofe Jesu)
Gbogbo agbaye ni wo n ti ṣe isoji ọpẹ (ore ofe Jesu ati anu lo n to mi leyin)
Alayo ni mi o, ore ofe ati anu
Lo n to wa oh at’ẹmi atilemi leyin oh
Bi mo ba jade, bi mo ba wole (ire Ire)
Bi mo ba sun lale ti mo ji lowuro (ire ire)
Adawole mi ko yori Si ogo (ire ire)
Ore ofe Jesu kristi ati anu lo deyin leyin mi (ire ire)
Oro mi ma sope ni gbogbo ona ni o (ire ire)
Ibi ti mo ba tẹ a sun rere fun mi (ire ire)
Ire níwájú mi, ire leyin ire lorun lo fún mi (ire ire)
Ayo legbe otun, legbe osi, níwájú leyin mi o (ire)
Ìfẹ oluwa Jesu kristi ko le fi mi silẹ lai lai (ire)
Ore ofe Jesu
Ore ofe Jesu (o to mi leyin, o bami gbe, o bami sun, o bami lo)
Ore ofe Jesu ati anu lo n to mi leyin
Gbogbo ibi ti mo ba tẹ (ore ofe Jesu)
Mo gba bẹ nile (ore ofe Jesu)
Anu wa mi ri, ore ofe sare tẹ mi leyin(ore ofe Jesu ati anu lo n to mi leyin)
Olorun lo se mi bẹ
Ni tooto ki ire ati anu ore ofe
Ko ma to ọ lẹyin ni gbogbo ọjọ ayé rẹ
Adura ojo pipe ko gba esi ayo logan (amin o)
Alanu ko wa e ri, ko ma se laala lasan
O ni se mú fún ota, bẹẹni o ni teni tika laye ti o wa o
Awotele rẹ àti tode yo ma bi ogo fun ọ ní
Ore ofe ati ìfẹ ọlọrun ko ma ko ti wa pa (ko ma ko tiwa pa)
Ore ofe Jesu
Ore ofe Jesu (etewo adura mo wí o)
Ore ofe Jesu ati anu lo n to mi leyin (ore ofe ati anu, ojurere ati ìfẹ oluwa ko ma tẹle wa)
Ore ofe Jesu
Ore ofe Jesu
Ore ofe Jesu ati anu lo n to mi leyin
Ore ofe Jesu (awa lo sale)
Ore ofe Jesu (awa lo da fún)
Ore ofe Jesu ati anu lo n to mi leyin (ohun lo de mi fún, inu rẹ ni mo ti je mo ti mú)
Bàbá lo se be